Ẹ̀BÁ Ọ̀DÀN (ÌBÀDÀN)
Lágelú - ILÉ IFẸ̀
Máyè Okúnadé - ILÉ IFẸ̀
Ọmọ ọkọ Ìbàdàn tó bá bú Ilé Ifẹ̀ fi ọwọ́ òsì júwe orírun àwọn Baba tó bíi l'ọ́mọ ni .
Síbẹ̀ síbẹ̀ àwọn kan a máa lanu pàgà bíi pàkúté ọlọ́gàn wípé kíni Ilé Ifẹ̀ ṣe láti dáàbò bo ilẹ̀ Yorùbá .
Àì mọ̀'tàn kò jẹ́ kí wọn ó mọ̀ wípé nínú ìkòkò dúdú ni ẹkọ funfun ti jáde .
Mo maa nsọ fun yín ní gbogbo ìgbà wípé , tí ẹ bá bu ẹnu àtẹ́ lu Ọba kan , gbogbo Ọmọ Yorùbá la bu àtẹ́ lù .
Kí adé pẹ́ lórí o Baba wa Olúbàdàn titun HRM , Ọba Adéwọ̀lú Ládọjà.
*Olubadan's since 1820*
1. Lágelú (1820)
2. Baálẹ̀ Máyẹ̀ Okùnadé (1820-1826)
3. Baálẹ̀ Oluyendun Labosinde (1826-1830)
4. Baale Lákanlẹ̀ (1830-1835)
5. Basorun Olúyọ̀lé Ojaba (1835-1850)
6. Baale Oderinlo Opeagbe Idiomo/Kure (1850-1851)
7. Baale Oyesile Olugbode Ita Baale (1851-1864)
8. Ba’ale Ibikunle (1864-1865)
9. Basorun Ogumola Mapo (1865-1867)
10. Balogun Beyioku Akere Onitamperin (1867-1870)
11. Baale Orowusi (Awarun) Kobomoje (1870-1871)
12. Aare Oladoke Latoosa Oke-Are (1871-1885)
13. Balogun Ajayi Osungbekun Kobmoje (1885-1893)
14. Baate Fijabi 1 (Omo Babalola) Oritamerin (1893-1895)
15. Baale Osuntoki Olusun Agbeni (1895-1897)
16. Badorun Fajimi (Yerombi) Oranyan (1897-1902)
17. Baale Mosaderin Sunlehinmi Oranyan (1902-1904)
18. Baale Dada Opadare Mapo (1904-1907)
19. Basorun Sumonu Apanpa Isale-Osi (1907-1910).
20. Baale Akintayo Awanibaku Elenpe Bere, Aboke (1910-1912)
21. Baale Irefin (Omo Ogundeyi) Oke Ofa Babasale (1912-1914)
22. Baale Shitu (Omo Are Latosa) Oke Are (1914-1925)
23. Baale Oyewole Aiyejenku Omo Foko Oke Foko (1925-1930)
24. Olubadan Okunola Abaasi Alesinloye Isale Ijebu (1930-1946)
25. Olubadan Fagbinrin Akere II Oritamerin (1946)
26. Olubadan Oyetunde I Eleta (1946)
27. Olubadan Akintunde Bioku Oleyo, Oranyan (1947-1948)
28. Olubadan Fijabi II Oritamerin (1948-1952)
29. Olubadan Memudu Alli Iwo Gbenla (1952)
30. Olubadan Igbintade Apete Oke Ofa (1952-1955)
31. Oba Isaac Babalola Akinyele Alafara (1955-1964)
32. Oba Yesufu Kobiowu Oranyan (1964)
33. Oba Salawu Akanbi Aminu Adeoyo (1965-1971)
34. Oba Shittu Akintola Oyetunde II Eleta (1971-1976)
35. Oba Gbadamosi Akanbi Adebimpe Odinjo (1976-1977)
36. Oba Daniel Tayo Akinbiyi Elekuro (1977-1982)
37. Oba Yesufu Oloyede Asanike IdiAro (1983-1993)
38. Oba Emmanuel Adegboyega Operinde Isale Ijebu (1993-1999)
39. Oba Yinusa B. Ogundipe Arapasowu I Oranyan (1999-2007)
40. Oba Samuel Odulana Olugade I
(2007-2016)
41. Oba Saliu Akanmu Adetunji (2016-2022)
42. Oba Lekan Balogun (2022-2024)
43. Oba Owolabi Olakulehin (2024-2025)
Ọba Ràṣídì Ládọjà is the 44th olubadan